Òwe 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Pàṣán wà fún ẹṣin, ìjánu wà fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,+Ọ̀pá sì wà fún ẹ̀yìn àwọn òmùgọ̀.+