Òwe 15:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Onínúfùfù máa ń dá wàhálà sílẹ̀,+Àmọ́ ẹni tí kì í tètè bínú máa ń mú kí ìjà rọlẹ̀.+