-
Ẹ́sítà 6:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tí Hámánì wọlé, ọba béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ló yẹ ká ṣe fún ọkùnrin tó wu ọba pé kó dá lọ́lá?” Hámánì sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Ta ni ọba tún fẹ́ dá lọ́lá tí kì í bá ṣe èmi?”+
-
-
Ẹ́sítà 6:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Lójú ẹsẹ̀, ọba sọ fún Hámánì pé: “Ṣe kíá! Mú ẹ̀wù oyè àti ẹṣin náà, kí o sì ṣe ohun tí o sọ yìí fún Módékáì, Júù tó ń jókòó ní ẹnubodè ọba. Má yọ ìkankan sílẹ̀ nínú gbogbo ohun tí o sọ.”
-