Mátíù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Fún wa ní oúnjẹ òòjọ́ wa lónìí;+ 1 Tímótì 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, tí a bá ti ní oúnjẹ* àti aṣọ,* àwọn nǹkan yìí máa tẹ́ wa lọ́rùn.+