Òwe 6:6-8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tọ èèrà lọ, ìwọ ọ̀lẹ;+Kíyè sí àwọn ọ̀nà rẹ̀, kí o sì gbọ́n. 7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ní olùdarí, aláṣẹ tàbí alákòóso, 8 Ó ń ṣètò oúnjẹ rẹ̀ sílẹ̀ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn,+Ó sì ń kó oúnjẹ rẹ̀ jọ nígbà ìkórè.
6 Tọ èèrà lọ, ìwọ ọ̀lẹ;+Kíyè sí àwọn ọ̀nà rẹ̀, kí o sì gbọ́n. 7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ní olùdarí, aláṣẹ tàbí alákòóso, 8 Ó ń ṣètò oúnjẹ rẹ̀ sílẹ̀ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn,+Ó sì ń kó oúnjẹ rẹ̀ jọ nígbà ìkórè.