Òwe 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ọmọ mi, fetí sí ìbáwí bàbá rẹ,+Má sì pa ẹ̀kọ́* ìyá rẹ tì.+ 2 Tímótì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí mo rántí ìgbàgbọ́ rẹ tí kò ní ẹ̀tàn,+ èyí tí ìyá rẹ àgbà Lọ́ìsì àti ìyá rẹ Yùníìsì kọ́kọ́ ní, ó sì dá mi lójú pé irú ìgbàgbọ́ yìí ni ìwọ náà ní.
5 Torí mo rántí ìgbàgbọ́ rẹ tí kò ní ẹ̀tàn,+ èyí tí ìyá rẹ àgbà Lọ́ìsì àti ìyá rẹ Yùníìsì kọ́kọ́ ní, ó sì dá mi lójú pé irú ìgbàgbọ́ yìí ni ìwọ náà ní.