Òwe 6:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ohun mẹ́fà wà tí Jèhófà kórìíra;Bẹ́ẹ̀ ni, ohun méje tó jẹ́ ohun ìríra fún un:* 17 Ojú ìgbéraga,+ ahọ́n èké+ àti ọwọ́ tó ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+
16 Ohun mẹ́fà wà tí Jèhófà kórìíra;Bẹ́ẹ̀ ni, ohun méje tó jẹ́ ohun ìríra fún un:* 17 Ojú ìgbéraga,+ ahọ́n èké+ àti ọwọ́ tó ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+