-
1 Àwọn Ọba 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀, ní kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀, ìjọba rẹ̀ fìdí múlẹ̀ gbọn-in.+
-
-
2 Kíróníkà 9:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Sólómọ́nì fi ogójì (40) ọdún jọba ní Jerúsálẹ́mù lórí gbogbo Ísírẹ́lì.
-