Oníwàásù 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo fi ọkàn mi sí mímọ ọgbọ́n àti sí rírí gbogbo ohun* tó ń lọ nínú ayé,+ kódà mi ò fojú ba oorun* ní ọ̀sán tàbí ní òru.
16 Mo fi ọkàn mi sí mímọ ọgbọ́n àti sí rírí gbogbo ohun* tó ń lọ nínú ayé,+ kódà mi ò fojú ba oorun* ní ọ̀sán tàbí ní òru.