ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 10:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ìrántí* olódodo yẹ fún ìbùkún,+

      Àmọ́ orúkọ àwọn ẹni burúkú yóò jẹrà.+

  • Òwe 22:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Orúkọ rere* ló yẹ kéèyàn yàn dípò ọ̀pọ̀ ọrọ̀;+

      Kéèyàn níyì* sàn ju fàdákà àti wúrà.

  • Àìsáyà 56:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 “Màá fún wọn ní ohun ìrántí àti orúkọ ní ilé mi àti lára àwọn ògiri mi,

      Ohun tó dára ju àwọn ọmọkùnrin àtàwọn ọmọbìnrin.

      Màá fún wọn ní orúkọ tó máa wà títí láé,

      Èyí tí kò ní pa run.

  • Lúùkù 10:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ṣùgbọ́n, ẹ má yọ̀ torí pé a mú kí àwọn ẹ̀mí tẹrí ba fún yín, àmọ́ ẹ yọ̀ torí pé a ti kọ orúkọ yín sílẹ̀ ní ọ̀run.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́