Oníwàásù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo sọ nípa ẹ̀rín pé, “Wèrè ni!” Àti nípa ìgbádùn* pé, “Kí ni ìwúlò rẹ̀?”