Òwe 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+ Jémíìsì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+
32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+
19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+