-
Òwe 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+
Àti ẹni tó ní òye;
-
Òwe 3:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Igi ìyè ni fún àwọn tó dì í mú,
Aláyọ̀ ni a ó sì máa pe àwọn tó dì í mú ṣinṣin.+
-
-
-