Jóòbù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ Jóòbù sọ fún un pé: “Ò ń sọ̀rọ̀ bí ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí kò nírònú. Tí a bá gba ohun rere lọ́wọ́ Ọlọ́run tòótọ́, ṣé kò yẹ ká tún gba ohun búburú?”+ Nínú gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí, Jóòbù kò fi ẹnu rẹ̀ dẹ́ṣẹ̀.+ Àìsáyà 45:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.
10 Àmọ́ Jóòbù sọ fún un pé: “Ò ń sọ̀rọ̀ bí ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí kò nírònú. Tí a bá gba ohun rere lọ́wọ́ Ọlọ́run tòótọ́, ṣé kò yẹ ká tún gba ohun búburú?”+ Nínú gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí, Jóòbù kò fi ẹnu rẹ̀ dẹ́ṣẹ̀.+
7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.