ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 2:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Mo sọ nípa ẹ̀rín pé, “Wèrè ni!”

      Àti nípa ìgbádùn* pé, “Kí ni ìwúlò rẹ̀?”

      3 Mo mu wáìnì,+ kí n lè fi ọkàn mi ṣèwádìí, àmọ́ ní gbogbo àkókò yìí mi ò sọ ọgbọ́n mi nù; kódà, mo fara mọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ kí n lè rí ohun tó dáa jù lọ fún ọmọ aráyé láti máa ṣe láàárín ọjọ́ díẹ̀ tí wọ́n máa lò lábẹ́ ọ̀run.

  • Oníwàásù 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Mo wá fiyè sí ọgbọ́n àti ìwà wèrè àti ìwà ẹ̀gọ̀.+ (Kí ni ẹni tó máa wá lẹ́yìn ọba lè ṣe? Ohun tí àwọn èèyàn ti ṣe tẹ́lẹ̀ ni.)

  • Oníwàásù 7:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Mo darí ọkàn mi kí n lè mọ̀, kí n lè wádìí, kí n sì lè wá ọgbọ́n àti ohun tó ń fa àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀, mo sì darí rẹ̀ kí n lè lóye aburú tó wà nínú ìwà ẹ̀gọ̀ àti àìlọ́gbọ́n tó wà nínú ìwà wèrè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́