Oníwàásù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Ọlọ́run tòótọ́ yóò ṣe ìdájọ́ olódodo àti ẹni burúkú,+ nítorí àkókò wà fún gbogbo iṣẹ́ àti gbogbo akitiyan.”
17 Torí náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Ọlọ́run tòótọ́ yóò ṣe ìdájọ́ olódodo àti ẹni burúkú,+ nítorí àkókò wà fún gbogbo iṣẹ́ àti gbogbo akitiyan.”