Òwe 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìrántí* olódodo yẹ fún ìbùkún,+Àmọ́ orúkọ àwọn ẹni burúkú yóò jẹrà.+