ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 88:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ṣé àwọn òkú lo máa ṣe iṣẹ́ àgbàyanu hàn?

      Ṣé àwọn tí ikú ti pa* lè dìde wá yìn ọ́?+ (Sélà)

  • Sáàmù 115:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àwọn òkú kì í yin Jáà;+

      Bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú ìdákẹ́jẹ́ẹ́ ikú.*+

  • Sáàmù 146:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+

      Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+

  • Àìsáyà 38:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Torí pé Isà Òkú* ò lè yìn ọ́ lógo,+

      Ikú ò lè yìn ọ́.+

      Àwọn tó lọ sínú kòtò kò lè retí ìṣòtítọ́ rẹ.+

  • Jòhánù 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó fi kún un pé: “Lásárù ọ̀rẹ́ wa ti sùn,+ àmọ́ mò ń rìnrìn àjò lọ síbẹ̀ kí n lè jí i.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́