Dáníẹ́lì 10:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà yẹn, èmi Dáníẹ́lì ti ń ṣọ̀fọ̀+ fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko. 3 Mi ò jẹ oúnjẹ tó dọ́ṣọ̀, ẹran tàbí wáìnì kò kan ẹnu mi, mi ò sì fi òróró para rárá fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko.
2 Nígbà yẹn, èmi Dáníẹ́lì ti ń ṣọ̀fọ̀+ fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko. 3 Mi ò jẹ oúnjẹ tó dọ́ṣọ̀, ẹran tàbí wáìnì kò kan ẹnu mi, mi ò sì fi òróró para rárá fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta gbáko.