Òwe 31:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lémúẹ́lì, kò tọ́ sí àwọn ọba,Kò tọ́ kí àwọn ọba máa mu wáìnìTàbí kí àwọn alákòóso máa sọ pé, “Ọtí mi dà?”+ 5 Kí wọ́n má bàa mutí tán, kí wọ́n wá gbàgbé àṣẹ tó wà nílẹ̀,Kí wọ́n sì fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n.
4 Lémúẹ́lì, kò tọ́ sí àwọn ọba,Kò tọ́ kí àwọn ọba máa mu wáìnìTàbí kí àwọn alákòóso máa sọ pé, “Ọtí mi dà?”+ 5 Kí wọ́n má bàa mutí tán, kí wọ́n wá gbàgbé àṣẹ tó wà nílẹ̀,Kí wọ́n sì fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n.