-
Òwe 21:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ohun tó ń wu ọ̀lẹ ló máa pa á,
Nítorí pé ọwọ́ rẹ̀ kọ̀ láti ṣiṣẹ́.+
-
-
Òwe 24:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,
Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,
34 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,
Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+
-