Òwe 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀làwọ́* yóò gba ìbùkún,Nítorí ó ń fún aláìní lára oúnjẹ rẹ̀.+