-
Jẹ́nẹ́sísì 48:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ojú Ísírẹ́lì ti di bàìbàì torí ó ti darúgbó, kò sì ríran dáadáa. Jósẹ́fù mú wọn sún mọ́ ọ̀dọ̀ Ísírẹ́lì. Ísírẹ́lì fi ẹnu kò wọ́n lẹ́nu, ó sì gbá wọn mọ́ra.
-