-
Jẹ́nẹ́sísì 50:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jósẹ́fù wá lọ sin bàbá rẹ̀, gbogbo ìránṣẹ́ Fáráò sì bá a lọ, pẹ̀lú àwọn àgbààgbà+ ilé rẹ̀ àti gbogbo àgbààgbà ilẹ̀ Íjíbítì,
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 50:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Wọ́n wá dé ibi ìpakà Átádì, tó wà ní agbègbè Jọ́dánì, wọ́n sì ṣọ̀fọ̀ gidigidi níbẹ̀. Ọjọ́ méje ni Jósẹ́fù fi ṣọ̀fọ̀ bàbá rẹ̀.
-