Òwe 16:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọ̀rọ̀ dídùn jẹ́ afárá oyin,Ó dùn mọ́ ọkàn,* ó sì ń wo egungun sàn.+ Òwe 25:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bí àwọn èso ápù oníwúrà tó wà nínú abọ́* fàdákàNi ọ̀rọ̀ tí a sọ ní àkókò tí ó tọ́.+