1 Jòhánù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run túmọ̀ sí nìyí, pé ká pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́;+ síbẹ̀ àwọn àṣẹ rẹ̀ kò nira,+