-
Ìṣe 17:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn tó wà ní Bèróà ní ọkàn rere ju àwọn tó wà ní Tẹsalóníkà lọ, torí pé wọ́n gba ọ̀rọ̀ náà tọkàntọkàn wọ́n sì ń ṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ kínníkínní lójoojúmọ́ láti rí i bóyá àwọn nǹkan yìí rí bẹ́ẹ̀.
-