-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:62Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
62 Níbúṣánì, Ìlú Iyọ̀ àti Ẹ́ń-gédì,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́fà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
1 Sámúẹ́lì 23:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Lẹ́yìn náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì dúró sí àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Ẹ́ń-gédì.+
-