Orin Sólómọ́nì 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Mo lọ sínú ọgbà igi eléso,+Kí n lè rí ohun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ hù ní àfonífojì,Kí n lè rí i bóyá àjàrà ti hù,* Bóyá àwọn igi pómégíránétì ti yọ òdòdó.
11 “Mo lọ sínú ọgbà igi eléso,+Kí n lè rí ohun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ hù ní àfonífojì,Kí n lè rí i bóyá àjàrà ti hù,* Bóyá àwọn igi pómégíránétì ti yọ òdòdó.