-
Àìsáyà 18:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí kó tó di ìgbà ìkórè,
Tí ìtànná bá yọ tán, tí ìtànná òdòdó sì ti di èso àjàrà tó pọ́n,
Wọ́n máa fi ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn gé àwọn ọ̀mùnú rẹ̀ kúrò,
Wọ́n máa gé àwọn ọwọ́ rẹ̀ kúrò, wọ́n á sì kó o dà nù.
-