-
Àìsáyà 28:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Òdòdó ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,
Èyí tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá,
Máa dà bí àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́ ṣáájú ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn.
Tí ẹnì kan bá rí i, ṣe ló máa gbé e mì ní gbàrà tó bá ti wà lọ́wọ́ rẹ̀.
-
-
Náhúmù 3:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Gbogbo ibi olódi rẹ dà bí igi ọ̀pọ̀tọ́ tó ní àkọ́pọ́n èso;
Tí a bá mì í jìgìjìgì, àwọn èso náà máa já bọ́ sí ẹnu àwọn ọ̀jẹun.
-