Orin Sólómọ́nì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, mo dúdú lóòótọ́, àmọ́ òrékelẹ́wà ni mí,Bí àwọn àgọ́ tí wọ́n fi Kídárì ṣe,+ bí àwọn aṣọ àgọ́+ Sólómọ́nì. Orin Sólómọ́nì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ‘Ta ni obìnrin yìí tó ń tàn* bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Tó lẹ́wà bí òṣùpá àrànmọ́jú,Tó mọ́ rekete bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn,Tó gbayì gan-an bí àwọn ọmọ ogun tó yí ọ̀págun wọn ká?’”+
5 Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, mo dúdú lóòótọ́, àmọ́ òrékelẹ́wà ni mí,Bí àwọn àgọ́ tí wọ́n fi Kídárì ṣe,+ bí àwọn aṣọ àgọ́+ Sólómọ́nì.
10 ‘Ta ni obìnrin yìí tó ń tàn* bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Tó lẹ́wà bí òṣùpá àrànmọ́jú,Tó mọ́ rekete bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn,Tó gbayì gan-an bí àwọn ọmọ ogun tó yí ọ̀págun wọn ká?’”+