-
Orin Sólómọ́nì 8:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Tètè, olólùfẹ́ mi,
Kí o sì yára bí egbin+
Tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín
Lórí àwọn òkè tó ní ewé tó ń ta sánsán.”
-
14 “Tètè, olólùfẹ́ mi,
Kí o sì yára bí egbin+
Tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín
Lórí àwọn òkè tó ní ewé tó ń ta sánsán.”