-
Orin Sólómọ́nì 5:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn tó ń ṣọ́ ìlú rí mi nígbà tí wọ́n ń lọ yí ká.
Wọ́n lù mí, wọ́n ṣe mí léṣe.
Àwọn tó ń ṣọ́ ògiri ṣí ìborùn* mi kúrò lára mi.
-