ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 5:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Torí náà, Hírámù ránṣẹ́ sí Sólómọ́nì pé: “Mo ti gbọ́ iṣẹ́ tí o rán sí mi. Màá ṣe gbogbo ohun tí o fẹ́, màá fún ọ ní gẹdú igi kédárì àti igi júnípà.+ 9 Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kó wọn wá láti Lẹ́bánónì sí òkun, màá dì wọ́n ní àdìpọ̀ igi gẹdú kí ó lè gba orí òkun lọ sí ibi tí o bá ní kí n kó wọn sí. Màá ní kí wọ́n la àwọn igi náà níbẹ̀, kí o lè kó wọn lọ. Oúnjẹ tí mo bá béèrè fún agbo ilé+ mi ni wàá fi san án pa dà fún mi.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́