Òwe 5:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí orísun omi* rẹ ní ìbùkún,Kí o sì máa yọ̀ pẹ̀lú aya ìgbà èwe rẹ,+19 Abo àgbọ̀nrín tó fani mọ́ra, ewúrẹ́ rírẹwà orí òkè.+ Jẹ́ kí ọmú rẹ̀ máa dá ọ lọ́rùn* nígbà gbogbo. Kí ìfẹ́ rẹ̀ máa gbà ọ́ lọ́kàn ní gbogbo ìgbà.+
18 Kí orísun omi* rẹ ní ìbùkún,Kí o sì máa yọ̀ pẹ̀lú aya ìgbà èwe rẹ,+19 Abo àgbọ̀nrín tó fani mọ́ra, ewúrẹ́ rírẹwà orí òkè.+ Jẹ́ kí ọmú rẹ̀ máa dá ọ lọ́rùn* nígbà gbogbo. Kí ìfẹ́ rẹ̀ máa gbà ọ́ lọ́kàn ní gbogbo ìgbà.+