Orin Sólómọ́nì 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jẹ́ ká tètè jí, ká sì lọ sínú àwọn ọgbà àjàrà,Ká lọ wò ó bóyá àjàrà ti hù,* Bóyá òdòdó ti yọ,+Bóyá àwọn igi pómégíránétì ti yọ òdòdó.+ Ibẹ̀ ni màá ti fi ìfẹ́ hàn sí ọ.+
12 Jẹ́ ká tètè jí, ká sì lọ sínú àwọn ọgbà àjàrà,Ká lọ wò ó bóyá àjàrà ti hù,* Bóyá òdòdó ti yọ,+Bóyá àwọn igi pómégíránétì ti yọ òdòdó.+ Ibẹ̀ ni màá ti fi ìfẹ́ hàn sí ọ.+