Orin Sólómọ́nì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Wá fẹnu kò mí lẹ́nu,Torí ìfẹ́ tí ò ń fi hàn sí mi dára ju wáìnì lọ.+ Orin Sólómọ́nì 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mú mi dání;* jẹ́ ká sáré. Ọba ti mú mi wọnú àwọn yàrá rẹ̀ tó wà ní inú! Jẹ́ kí inú wa máa dùn, ká sì jọ máa yọ̀. Jẹ́ ká yin* ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tí ò ń fi hàn sí mi ju ọ̀rọ̀ wáìnì lọ. Abájọ tí wọ́n* fi nífẹ̀ẹ́ rẹ.
4 Mú mi dání;* jẹ́ ká sáré. Ọba ti mú mi wọnú àwọn yàrá rẹ̀ tó wà ní inú! Jẹ́ kí inú wa máa dùn, ká sì jọ máa yọ̀. Jẹ́ ká yin* ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tí ò ń fi hàn sí mi ju ọ̀rọ̀ wáìnì lọ. Abájọ tí wọ́n* fi nífẹ̀ẹ́ rẹ.