-
Orin Sólómọ́nì 4:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Jí, ìwọ atẹ́gùn àríwá;
Wọlé wá, ìwọ atẹ́gùn gúúsù.
Fẹ́* sórí ọgbà mi.
Jẹ́ kí ìtasánsán rẹ̀ gbalẹ̀ kan.”
“Jẹ́ kí olólùfẹ́ mi wá sínú ọgbà rẹ̀
Kó sì jẹ àwọn èso rẹ̀ tó dára jù lọ.”
-