Sáàmù 92:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ olódodo máa gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹWọ́n á sì tóbi bí igi kédárì ní Lẹ́bánónì.+