Orin Sólómọ́nì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ‘Ta ni obìnrin yìí tó ń tàn* bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Tó lẹ́wà bí òṣùpá àrànmọ́jú,Tó mọ́ rekete bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn,Tó gbayì gan-an bí àwọn ọmọ ogun tó yí ọ̀págun wọn ká?’”+
10 ‘Ta ni obìnrin yìí tó ń tàn* bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Tó lẹ́wà bí òṣùpá àrànmọ́jú,Tó mọ́ rekete bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn,Tó gbayì gan-an bí àwọn ọmọ ogun tó yí ọ̀págun wọn ká?’”+