Orin Sólómọ́nì 4:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn ẹ̀ka* rẹ dà bí ọgbà pómégíránétì,* Tó ní àwọn èso tó dára jù, àwọn ewé làálì pẹ̀lú ewé sípíkénádì,14 Sípíkénádì+ àti òdòdó sáfúrónì, pòròpórò*+ àti igi sínámónì,+Pẹ̀lú oríṣiríṣi igi tùràrí, òjíá àti álóè+Àti gbogbo lọ́fínńdà tó dára jù.+
13 Àwọn ẹ̀ka* rẹ dà bí ọgbà pómégíránétì,* Tó ní àwọn èso tó dára jù, àwọn ewé làálì pẹ̀lú ewé sípíkénádì,14 Sípíkénádì+ àti òdòdó sáfúrónì, pòròpórò*+ àti igi sínámónì,+Pẹ̀lú oríṣiríṣi igi tùràrí, òjíá àti álóè+Àti gbogbo lọ́fínńdà tó dára jù.+