-
Orin Sólómọ́nì 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ má tẹjú mọ́ mi torí pé mo dúdú,
Oòrùn ló sọ mí dà bẹ́ẹ̀.
Àwọn ọmọ ìyá mi bínú sí mi;
Wọ́n ní kí n máa bójú tó àwọn ọgbà àjàrà,
Àmọ́ mi ò bójú tó ọgbà àjàrà tèmi.
-