2 Kíróníkà 32:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó fi hàn,+ wọ́n wà lákọsílẹ̀ nínú ìran wòlíì Àìsáyà,+ ọmọ Émọ́ọ̀sì, nínú Ìwé Àwọn Ọba Júdà àti Ísírẹ́lì.+
32 Ní ti ìyókù ìtàn Hẹsikáyà àti ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó fi hàn,+ wọ́n wà lákọsílẹ̀ nínú ìran wòlíì Àìsáyà,+ ọmọ Émọ́ọ̀sì, nínú Ìwé Àwọn Ọba Júdà àti Ísírẹ́lì.+