Sáàmù 62:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+
9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+