Àìsáyà 66:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+
66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+