Ìdárò 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+
21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+