Àìsáyà 40:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Gbogbo orílẹ̀-èdè dà bí ohun tí kò sí ní iwájú rẹ̀;+Ó kà wọ́n sí ohun tí kò já mọ́ nǹkan kan, bí ohun tí kò sí rárá.+ Àìsáyà 60:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí orílẹ̀-èdè àti ìjọba èyíkéyìí tí kò bá sìn ọ́ máa ṣègbé,Àwọn orílẹ̀-èdè sì máa pa run pátápátá.+
17 Gbogbo orílẹ̀-èdè dà bí ohun tí kò sí ní iwájú rẹ̀;+Ó kà wọ́n sí ohun tí kò já mọ́ nǹkan kan, bí ohun tí kò sí rárá.+
12 Torí orílẹ̀-èdè àti ìjọba èyíkéyìí tí kò bá sìn ọ́ máa ṣègbé,Àwọn orílẹ̀-èdè sì máa pa run pátápátá.+