Àìsáyà 51:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Òdodo mi sún mọ́lé.+ Ìgbàlà mi máa jáde lọ,+Apá mi sì máa dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́.+ Àwọn erékùṣù máa nírètí nínú mi,+Wọ́n sì máa dúró de apá* mi.
5 Òdodo mi sún mọ́lé.+ Ìgbàlà mi máa jáde lọ,+Apá mi sì máa dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́.+ Àwọn erékùṣù máa nírètí nínú mi,+Wọ́n sì máa dúró de apá* mi.