Àìsáyà 59:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó wá gbé òdodo wọ̀ bí ẹ̀wù irin,Ó sì dé akoto ìgbàlà* sí orí rẹ̀.+ Ó wọ ẹ̀wù ẹ̀san bí aṣọ,+Ó sì fi ìtara bo ara rẹ̀ bí aṣọ àwọ̀lékè.*
17 Ó wá gbé òdodo wọ̀ bí ẹ̀wù irin,Ó sì dé akoto ìgbàlà* sí orí rẹ̀.+ Ó wọ ẹ̀wù ẹ̀san bí aṣọ,+Ó sì fi ìtara bo ara rẹ̀ bí aṣọ àwọ̀lékè.*